DOWNLOAD: Sola Allyson – Mo Gbola Wa [Mp3, Lyrics & Video]

VIDEO: Sola Allyson – Mo Gb’ola Wa
LYRICS: Sola Allyson – Mo Gbola Wa
Iba Si Olorun Si Eledumare
Gbogbo ise Ajuba
Iba Olola to ju Olola
Eni to dami ti mo se wo
Gbogbo Ise loun bu ola fun o mo join won oba wa
Iba Olola to ju Olola
Eni to dami ti mo se wo
Gbogbo Ise loun bu ola fun o mo join won oba wa
(Chorus)
MoGbo lawa
MoGbo lawa
MoGbo lawa
Fun Aye raye
Bo ti nbe lo mo be
Ole yipada Ayeraye
Ole yipada Ayeraye
Ole yipada Ayeraye
Ole yipada Ayeraye
Bo ti nbe lo mo be
Ole yipada Ayeraye
Iba re Oba tolaye
Iba fun o Oba to lorun
Ori Ite Lojokole
Lo ti npase ayeraye
Nipa se re nilekun Ojo nsi